Lyrics: Eyin Lese – Felix Ajaguna (Abanise 1) Lyrics
Eyin lese ooo, Olorun
Eyin lese ooo, Olorun
Eyin Lese
Biku see fo mi da ooo
Olorun eyin lese
Olorun ema ma see
Vocal: Nigba taye gbogun de ooo
Ti mi ko re ni kan kan
Eyin Mori
Nigba tesu gbogun dide
Ti ko o salabaro kankan
Eyin Mori
IPA toju IPA lo eseun
Oro to ju Oro lo , ema ma see..
Chrs: Eyin lese ooo, Olorun
Eyin lese
Eyin lese ooo, Olorun
Eyin lese biku see foo mi dao
Olorun eyin lese
Barun se foo mi da.
End of Eyin Lese – Felix Ajaguna (Abanise 1) Lyrics
Eyin Lese – Felix Ajaguna (Abanise 1) Lyrics
Eyin Lese – Felix Ajaguna (Abanise 1) Lyrics
Eyin Lese – Felix Ajaguna (Abanise 1) Lyrics
Eyin Lese – Felix Ajaguna (Abanise 1) Lyrics
Eyin Lese – Felix Ajaguna (Abanise 1) Lyrics